Jump to content

Helen Asemota

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Helen Nosakhare Asemota jẹ́ Baokẹ́mísítì àti Baotẹkinọ́lọ́gísìtì nípa nǹkan ọ̀gbìn tó wà ní Jamaica. Ó Jẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n fún Baokẹ́mísítì àti Mòlẹ́kúlà Bìólójì àti Ádárì fún sẹ́ńtà Baotẹkinọ́lọ́gísìtì fún Fáṣítì West Indies ní Mona, Jamaica. Àwọn ìwádìí rẹ̀ mú ìlọsíwájú bá Baotẹkinọ́lọ́gísìtì nípa bí wọ́n ṣe máa ń ṣe nǹkan àti Ìtẹ̀síwájú bá àwọn nǹkan èso-oko. Ó Jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tó wà ní iwájú fún ìbáṣẹpọ̀ Baotẹkinọ́lọ́gísìtì ní Àgbáláayé, bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ ẹni tí wọ́n máa ń gbà ìmọ̀ràn lọ́wọ́ rẹ̀ ní gbogbo ayé lórí Baotẹkinọ́lọ́gísìtì fún United Nations (UN).

Ayé àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Asemota ní Nàìjíríà.[1] Ó gbà òye ìparí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Fásitì Benin, Ó gba òye Másítàsì lórí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ sáyẹ́nsì ní Fásitì Àhmádù Béllò, àti Dọ́kítà ní Fìlọ́sọ́fì ní Fáṣítì Benin/Fásitì Frankfurt .[1][2]

Awọ̀n Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 "UWI yam research poised to boost bioeconomic Growth". The Jamaica Gleaner. 6 August 2007. https://www.pressreader.com/jamaica/jamaica-gleaner/20170806/282905205646652. 
  2. "UWI Mona Research Engine [beta]". mord.mona.uwi.edu. Archived from the original on 2019-01-19. Retrieved 2018-11-09.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)