Henrietta Ogan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Henrietta Ogan jẹ́ alámójútó okùn òwò tí ó sì jẹ́ ààrẹ Ahmadu Bello University Alumni Association. Ó fi ipò yìí sílẹ̀ fún  Ahmed Tijani Mora, ogbónta onímọ̀ oògùn oyìnbó  tí ó jẹ́ alákóso  Pharmacists Council of Nigeria.[1][2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]