Hifikepunye Pohamba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Hifikepunye Lucas Pohamba
Hifikepunye Pohamba.jpg
President of Namibia
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
21 March 2005
Alákóso Àgbà Nahas Angula
Asíwájú Sam Nujoma
Personal details
Ọjọ́ìbí 18 Oṣù Kẹjọ 1935 (1935-08-18) (ọmọ ọdún 84)
Okanghudi, Namibia
Ẹgbẹ́ olóṣèlu SWAPO
Spouse(s) Penehupifo Pohamba

Hifikepunye Lucas Pohamba (ojoibi August 18, 1935) je oloselu omo ile Namibia. Lowolowo ohun ni Aare Orile-ede Namibia. Won koko diboyan wole ni 2004, o si tun pade yori ninu idiboyan to waye ni 27 ati 28 November, 2009. Egbe oloselu SWAPO ti Pohamba je olori gba 77.82% ibo.[2]Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]