Hilda Dokubo
Hilda Dokubo | |
---|---|
Dokubo crying while speaking on how hunger affects poor people at the HungerFREE Campaign of ActionAid in 2007 | |
Ọjọ́ìbí | Buguma, Asari-Toru, ìpínlẹ̀ Rivers |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | òṣèrébìnrin |
Hilda Dokubo tí a tún mọ̀ sí Hilda Dokubo Mrakpor jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ àwọn ọ̀dọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó ti fìgbà kan jẹ́ olùgbaninímọ̀ràn pàtàkì lórí ọ̀rọ̀ ọ̀dọ́ fún Gómìnà àná ìpínlẹ̀ Rivers, Peter Odili.[1][2]
Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí ní Hilda Dokubo, tí ó jẹ́ àkọ́bí fún àwọn òbí rẹ̀ ìlú Buguma, ní Asari-Toru, ìpínlẹ̀ Rivers, níbi tí ó ti kàwé àkóbẹ̀rẹ̀ àti sẹ́kọ́ndìrì ní ilé ìwé St Mary State School, lópópónà Aggrey àti Government Girls Secondary School.[3] Ó kẹ́kọ̀ọ́ gbàwé ẹ̀rí dìgírì àkọ́kọ́ àti ìkejì nínú ìmọ̀ iṣẹ́ Tíátà ní ifáfitì.[3]
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Nígbà ìsìnlú, iṣẹ́ àgùnbánirọ̀ ni Dokubo kópa nínú sinimá àgbéléwò àkọ́kọ́ tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Evil Passion lọ́dún 1992. Láti ìgbà náà ló ti di gbajúmọ̀ òṣèré ìlúmọ̀ọ́kà nínú sinimá àgbéléwò, tí ó sìn ti ṣe olóòtú ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá àgbéléwò lédè Gẹ̀ẹ́sì àti Ìgbò.[4] Lọ́dún 2015, Dokubo gba àmìn ẹ̀yẹ tí Africa Movie Academy fún ipa ẹ̀dá ìtàn tí ó kó nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Stigma. [5]
Àtòjọ Àwọn sinimá àgbéléwò rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Without Love
- Forever (1995)
- Jezebel
- Evil Passion(1996)
- Hour of Grace
- Error of the Past (2000)
- Sweet Mother (2000)
- Black Maria (1997)
- End of the Wicked (1999)
- "Confidence"
- Onye-Eze (2001)
- My Good Will (2001)
- Light & Darkness (2001)
- A Barber's Wisdom (2001)
- My Love (1998)
- Above Death: In God We Trust (2003)
- World Apart (2004)
- With God (2004)
- Unfaithful (2004)
- Chameleon (2004)
- 21 Days With Christ (2005)
- Gone Forever (2006)
- Stigma (2013)
- The CEO (2016)
Fatal
Àwọn àmìn ẹ̀yẹ tí ó gbà àti tí wọ́n yàn án fún
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Orúkọ afúnni lámìn-ẹ̀yẹ | Àmín ẹ̀yẹ | Èsì | Àwọn Ìtọ́kasí |
---|---|---|---|---|
2015 | Àmìn ẹ̀yẹ sinimá àgbéléwò Áfíríkà ẹlẹ́ẹ̀kọkànlá | Òṣèrébìnrin tó dára jùlọ fún amúgbalẹ́gbẹ̀ẹ́ olú-ẹ̀dá ìtàn | Gbàá | [6] |
Àjọ̀dún ẹlẹ́ẹ̀kejìlá sinimá àgbéléwò àgbáyé tí Àbújá | Òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò tó dára jùlọ | Gbàá | [7] |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Hilda Dokubo stages come back to screen". The Sun Newspaper. 9 April 2016. http://sunnewsonline.com/hilda-dokubo-stages-come-back-to-screen/. Retrieved 2 June 2016.
- ↑ Uwandu, Elizabeth (7 May 2015). "I set pace for entertainers to hold political office – Hilda Dokubo". Vanguard Newspaper. http://www.vanguardngr.com/2015/05/i-set-pace-for-entertainers-to-hold-political-office-hilda-dokubo/. Retrieved 2 June 2016.
- ↑ 3.0 3.1 Izuzu, Chidumga (23 October 2015). "Hilda Dokubo: 6 things you probably don't know about talented Veteran". Pulse Nigeria. Archived from the original on 5 February 2020. Retrieved 2 June 2016.
- ↑ Njoku, Benjamin (3 October 2015). "What fame has done for me — Hilda Dokubo". Vanguard Newspapaper. http://www.vanguardngr.com/2015/10/what-fame-has-done-for-me-hilda-dokubo/. Retrieved 2 June 2016.
- ↑ Adesola Ade-Unuigbe (21 August 2015). "See Full List of 2015 Africa Movie Academy Awards (AMAA) Nominees | OC Ukeje, Hilda Dokubo, Ini Edo & More". BellaNaija. Retrieved 2 June 2016.
- ↑ Husseini, Shaibu (2 October 2015). "AMAA 2015: And The Award For The Leading Actor, Supporting Actress And Promising Actor Goes To …". The Guardian Newspaper. Archived from the original on 19 October 2020. https://web.archive.org/web/20201019005702/https://m.guardian.ng/saturday-magazine/amaa-2015-and-the-award-for-the-leading-actor-supporting-actress-and-promising-actor-goes-to/. Retrieved 5 June 2016.
- ↑ Abulude, Samuel (6 November 2015). "Nigeria: Hilda Dokubo, IK Ogbonna Pick Best Actor Awards At 12th AIFF". Leadership Newspaper (AllAfrica). http://allafrica.com/stories/201511060218.html. Retrieved 2 June 2016.