Hind Bensari
Ìrísí
Hind Bensari هند بن ساري | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Hind Bensari 1987 Casablanca, Morocco |
Orílẹ̀-èdè | Moroccan Danish |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Edinburgh University London School of Economics and Political Science |
Iṣẹ́ | Director, TEDx speaker |
Ìgbà iṣẹ́ | 2013–present |
Hind Bensari (tí wọ́n bí ní ọdún 1987) jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Mòrókò.[1][2] Ó gbajúmọ̀ fún dídarí àwọn eré bíi 475: Break the Silence àti We Could Be Heroes.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Hind Bensari". Tribeca Film Festival. Retrieved 8 October 2020.
- ↑ "Hind Bensari: director". MUBI. Retrieved 8 October 2020.
- ↑ "Moroccan Filmmaker Hind Bensari Wins Documentary Award in Canada". Morocco World News. Retrieved 8 October 2020.
Àwọn ìtakùn Ìjásóde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- We Could Be Heroes Archived 2023-08-28 at the Wayback Machine.