Hlonipha Mokoena
Ìrísí
Hlonipha Mokoena jẹ òpìtàn ilẹ̀ South Africa, ní Wits Institute for Social and Economic Research ti University of the Witwatersrand. Ó jẹ́ alámọ̀já nínú ìtàn àkọọ́lẹ̀ ti South Africa.[1] Ó fìgbà kan ṣiṣẹ́ ní ẹ̀ka ìmọ̀-ẹ̀dá ènìyàn ní Columbia University.[2] Ó gba oyè PhD ní University of Cape Town ní ọdún 2005. [3] Ìwé rẹ̀, ìyẹn, Magema Fuze: The Making of a Kholwa Intellectual, dá lórí Magema Magwaza Fuze, tó jẹ́ agbọ̀rọ̀sọ ti Zulu àkọ́kọ́ tó máa ṣe àtẹ̀jáde ìwé nínú èdẹ̀ náà.[4][5]
Àtòjọ àwọn ìwé tó ti tẹ̀jáde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- "An Assembly of Readers: Magema Fuze and His Ilanga Lase Natal Readers", Journal of Southern African Studies, Vol. 35, No. 3 (Sep., 2009), pp. 595–607.
- Magema Fuze: The Making of a Kholwa Intellectual. University of KwaZulu-Natal PreISBN 978-1869141912ss, 2011. ISBN 978-1869141912
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Hlonipha Mokoena". Socialdifference.columbia.edu. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ "Hlonipha Mokoena - Wits Institute for Social and Economic Research". Wiser.wits.ac.za. Archived from the original on 29 July 2018. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ "Hlonipha Mokoena". The Conversation. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ "Hlonipha Mokoena « Black Portraiture[s] Conferences". Blackportraitures.info. Archived from the original on 30 July 2018. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Tallie, T.J.; Couper, Scott (1 January 2012). "Hlonipha Mokoena. Magema Fuze: The Making of a Kholwa Intellectual. Moss Mashamaite, The Second Coming: The Life and Times of Pixley ka Isaka Seme, The Founder of the ANC". Journal of Natal and Zulu History 30 (1): 101–106. doi:10.1080/02590123.2012.11964180.