Jump to content

Homonu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Homonu jẹ kemikali ti àwon glandì kòkan ninú ara n se láti fofin si isé seeli àti àwon eya ara kòkan. Èjè tàbí ìsàn(fluid) ara lóma ún gbé homonu láti ìbí tí a ti sé ló sí ibi tí o ti ma sisé. Homonu le fofin sí bí ènìyàn tàbí eranko se ún dàgbà, jeun, wúwà tàbí sun, nígbà ti okunrin bá ún balaga, homunu ni oun mú kí ohùn re ki tàbí ti irun wà ní abíyá, ikùn, ojú àti àwon èyà ara míràn, homonu sì ló ún mú kí obinrin wu omú, òun sì ló ún mú kí irun wu labiya obinrin àti igba tí nkan osu obinrin ma bere sí ún wa[1] . Àwon glandì tí oun se homonu ninú ara ni àún pè ní "endocrine gland", ìbàjé fún won si le jé ewu nlá fún ara.

Apere Homonu inú ara eniyan

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Testosterone

Estrogen

Progesterone

• Growth hormone

Oxytocin

  1. "Puberty - Hormonal Changes - Physical Changes". TeachMePhysiology. 2021-11-04. Retrieved 2022-02-25.