Honey dew (melon)
Ìrísí
Honeydew melon jẹ́ ọ̀kan lára méjì nínú gbòógì oríṣi èso tí a yàn gbìn ní ọ̀wọ́ èso Cucumis melo Inodorus.[1] Àbùdà a rẹ̀ jẹ́ èyí tí ó nípọn, tí ó dán, tí kò sí ní òórùn dídùn. Èyí tó jé èkejì nínú ọ̀wọ́ yìí ni wrinkle-rind casaba melon.[2]
Àbùdá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Honey dew ní àbùdá roboto, ó sì gùn ní ìwọn mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n sí mejìlélógún sẹ̀ǹtímítà. Ní kárí, ó máa ń gbé ìwọ̀n kílógírámù 1.8 sí 3.6.[3] Èèpo rẹ̀ máa ń jẹ́ àwọ̀ ewéko fẹ́rẹ́fẹ́, tí èpò dídán rẹ̀ sì máa ń jẹ́ yálà àwọ̀ ewéko tàbí ti ìtànná òrùn. Bí i àwọn èso tó kù, èso yìí máa ń ní kóro. A máa ń jẹ tínu èso yìí, lọ́pọ̀ ìgbà lẹ́yìn oúnjẹ, àti pé a tún le rí i ní àwọn ilé-ìtajà káàkiri lágbàáye. Ní California, honey dew máa ń wà láàrin osù kẹjọ sí oṣù kẹwàá.[4]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Stephens, James M. (2018-11-01). "Melon, Honeydew—Cucumis melo L. (Inodorus group)". Minor Vegetables Handbook. University of Florida, Institute of Food and Agricultural Sciences Extension. Retrieved 2021-01-25.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Stephens, James M. (2018-11-01). "Melon, Casaba—Cucumis melo L. (Inodorus group)". Minor Vegetables Handbook. University of Florida, Institute of Food and Agricultural Sciences Extension. Archived from the original on 2021-02-12. Retrieved 2021-01-25.
- ↑ A Comprehensive Visual Guide: What Does a Honeydew Melon Look Like and How to Identify It. What Does a Honeydew Melon Look Like: A Visual Guide.
- ↑ Honeydews Archived 2017-05-06 at the Wayback Machine.. Producepete.com. Retrieved on 2015-04-22.