Honiara

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Honiara
Main Street, Honiara
Main Street, Honiara
Country Solomon Islands
ProvinceHoniara Town
IslandGuadalcanal
Government
 • MayorAndrew Mua
Population
 (2003)
 • Total54,600
Time zoneUTC+11 (UTC)

Honiara, pelu iye eniyan to je 49,107 (1999), 54,600 (idiye 2003), ni oluilu awon Erekusu Solomoni ati fun igberiko Guadalkanal nibe. "Honiara" je oruko ti awon olumusin ara Ilegeesi si pe nitoripe o soro fun won lati pe ibe pelu oruko re gangan to n je Nagoniara. Nagoniara tumosi "niwaju iji."Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]