Jump to content

Hospital-acquired infection

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ilè iwosan

Akoran ti a ko lati ile iwosan, ti a tun mo si akoran nosokomia jẹ akoran ti a ko lati ile iwosan tabi ibi ti a ti n wo awon alaisan. [1] Lati le je ki awon eniyan mo iyato laarin awon akoran ti a ko ni ile iwosan ati eyi ti a o ko ni ile iwosan, a maa n pe ni akoran ile itoju.akoran ti ile itoju ilera .

 

  1. Rosenthal VD, et al. (2012). International Nosocomial Infection Control Consortium report, data summary of 36 countries, for 2004-2009. In: American Journal of Infection Control; 40(5):396-407. https://doi.org/10.1016/j.ajic.2011.05.020