Jump to content

House of wisdom

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ilé ọgbọ́n (The House of Wisdom) (Arabic: بَيْت الْحِكْمَة Bayt al-Ḥikmah), ní àwọn ènìyàn tún mọ̀ sí ilé-ìwé tí ó tóbi tí Baghdad (Grand Library of Baghdad),ní àwọn ènìyàn gbàgbọ́ pé ó jẹ́ ibi tí ó jé ilé ìwé ti gbogbogbò èyí tí ó yanrantí àti wí pé ó tún jẹ́ ibi tí ohun ọlọ́gbọ́n wà ní Baghdad. Ní ti ìtọ́kasí a máa ń tọ́ka rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí í ọ̀kan nínú àwọn ilé ìwé káàkiri àgbáyé èyí tí ó tóbi jù ní àsìkò Ọjọ́ orí tí ó níye lórí ti àwọn Mùsùlùmí (Islamic Golden Age),[1][2][3] tí a gbé kalẹ̀ yálà gẹ́gẹ́ bí i ilé ìwé fún àkójọpọ̀ ti Abbasid caliph Harun al-Rashid karùn-ún (r. 786–809) ní ìgbà sẹ́ńtúrì kẹjọ àbí gẹ́gẹ́ bí í aládani tí ó ń ṣe àkójọpọ̀ tí Abbasid caliph al-Mansur kejì (r. 754–775) lọ sí ibi tí àwọn ìwé tí ó ṣọ̀wọ́n wà àti ibi tí àwọn àkójọpọ̀ àwọn onírúurú ìwé wà èyí tí a kọ pẹ̀lú èdè Arábíìkì. Ní ìgbà tí Abbasid caliph al-Ma'mun (r. 813 – 833 AD), ẹlẹ́ẹ̀keje ń ṣe ìjọba, ní a yí i sí ilé ìwé àti ibi ètò ẹ̀kọ́ gbogbogbò gbogbogbò.[1][4]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Dimitri Gutas (1998). Greek Thought, Arabic Culture: The Graeco-Arabic Translation Movement in Baghdad and Early ʻAbbāsid Society (2nd–4th/8th–10th Centuries). Psychology Press. pp. 53–60. ISBN 978-0415061322. https://books.google.com/books?id=6cm_KK6Ubk8C&pg=PA53. 
  2. Jim Al-Khalili (2011). "5: The House of Wisdom". The House of Wisdom: How Arabic Science Saved Ancient Knowledge and Gave Us the Renaissance. Penguin Publishing Group. p. 53. ISBN 978-1101476239. https://books.google.com/books?id=aJ5zDM1KfewC&pg=PT53. 
  3. Chandio, Abdul Rahim (January 2021). "The house of wisdom (Bait Al-Hikmah): A sign of glorious period of Abbasids caliphate and development of science". International Journal of Engineering and Information Systems. ISSN 2643-640X. https://www.academia.edu/45652201. Retrieved 2022-07-09.