Iṣẹ́ Àgbẹ̀ ní Nàìjíríà
Ìrísí
Iṣẹ́ Àgbẹ̀ ní Nàìjíríà
Isé agbé jé isé tomodé tàgbà nílè yorúbá. Ó féré máa si ìràn ti kí i se ogbin àwon ounjé bí ìresì, èwà, isu, àgbàdo àti bee bee lo. Ipá pàtàki ni isé agbé n kó nínú eto oró ajé àti ìdàgbàsókè nàìjíríà lápapó. Àpeere re ni 'cocoa house' ti ìjoba ìwo oorun ko láyé ìjoba elékùnjekùn.[1]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Iwena, O. A. (Ed.) (2017). Essential Agricultural Science for Senior Secondary School. Tonad Publishers.
- ↑ Iwena, O. A. (Ed.) (2017). Essential Agricultural Science for Senior Secondary School. Tonad Publishers.