Iṣu Ewùrà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Iṣu Ewùrà tàbí Abo Iṣu tí wọ́n pè ní Dioscorea alata jẹ́ ẹ̀yà iṣu tí ó yatọ̀ sí àwọn ẹ̀yà iṣu tókù nípa fífà bí ilá tí óa ń fà nígbà tí wọ́n bá rin-ín. Ó sábà ma ń ní awọ̀ olómi aró sí lavender nígbà tí wọ́n bá haá làì tii bẹẹ́.[1]

Ìwúlò rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Yorùbá ma ń fi iṣu yí dárà oríṣiríṣi bí kí wọ́n fi se àsáró, díndín ọ̀jọ̀jọ̀, díndín jẹ, tàbí sísè jẹ lásán, àmọ́ wọn kìí fi gúnyán jẹ bí ti akọ iṣu.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "The Plant List: A Working List of All Plant Species". Archived from the original on 2021-06-16. Retrieved 2019-12-12. 
  2. "Isu ewura Archives". Sisi Jemimah (in Èdè Latini). 2016-01-22. Retrieved 2019-12-12.