Ibi ìwòràwọ̀ lati Vienna
Ìrísí
Ibi ìwòràwọ̀ lati Vienna () jẹ́ ibi tí wọ́n ti ń wòràwọ̀ lati orílẹ̀ èdè Vienna, ní Austria. Ó jẹ́ ara University of Vienna. Wọ́n kọ́ ibi ìwòràwọ̀ àkọ́kọ́ ní ọdún 1753 sí 1754 lórí òrùlé ìkan lára àwọn ilé tó wà ní yunifásitì yìí, tí Emperor Franz Joseph I of Austria pàṣẹ iṣàmúlò rẹ̀ ní ọdún 1883. Yàrá irinṣẹ́ rẹ̀ gangan tó àlàjá kan nínú 68 cm (27in) tí gígùn ìfojúsí rẹ̀ sì jẹ́ 10.5 metres (34 in) tí Grubb Telescope Company. kọ́. Ní ìgbà yẹn, òun ní irinṣẹ́ ìwòràwọ̀ tí ó tobi jùlọ.
Àwọn olùdarí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Maximilian Hell, 1756–1792
- Franz de Paula Triesnecker, 1792–1817
- Johann Josef von Littrow, 1819–1840
- Karl Ludwig von Littrow, 1842–1877
- Edmund Weiss, 1877–1908
- Kasimir Graff, 1928–1938
- Bruno Thüring, 1940–1945
- Kasimir Graff, 1945–1949
- Josef Hopmann, 1951–1962
- Josef Meurers, 1962–1979
- Karl Rakos, 1979–1981
- Werner Tscharnuter, 1981–1984
- Michel Breger, 1984–1986
- Paul Jackson, 1986–1994
- Michel Breger, 1994–2005
- Gerhard Hensler, 2006–2009
- Franz Kerschbaum, 2009–