Ibrahim Ahmad Maqary
Ìrísí
Sheikh Ibrahim Ahmad Maqary tí wọ́n bí ní September 15, ọdún 1976, ní Zaria, ní Ìpínlẹ̀ Kaduna, jé onímọ̀ Islam ní Nàìjíríà, tí ó gbajúmọ̀ fún àfikún rẹ̀ sí ẹ̀kọ́ Islam àti ìlànà ẹ̀sìn. Òun ni Imam Abuja National Mosque.[1][2][3]
Ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Maqary ní September 15, ọdún 1976, ní Zaria, ní Ìpínlẹ̀ Kaduna, ní Nàìjíríà. Ìdílé Mùsùlùmí tí ó kúndùn èkọ́ ni ó dàgbà sí. Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé Kéwú, níbi tí ó ti kọ́ Kùránì tí ó sì mọ̀ ọ́ lórí. Àwọn òbí rẹ̀ ran lọ sí Islamic institutions tó wà káàkiri Ìwọ̀ oòrùn ilè Africa, bí Senegal àti Mauritania.[4][5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ku San Malamanku tare da Sheik Ibrahim Ahmad Maqari". BBC News Hausa (in Èdè Hausa). 2021-02-05. Retrieved 2024-07-19.
- ↑ Hausa, Arewa Times (2022-04-03). "Tarihin Farfesa Ibrahim Ahmad Maqari". Arewa Times Hausa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-07-19.
- ↑ Abubakar, Fatimah Isah (2023-07-02). "Prof Maqari: Biography, Life and Legacy". Arewa House (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2024-07-20. Retrieved 2024-07-19.
- ↑ "Sheikh Professor Ibrahim Ahmad Maqari". The Muslim 500 (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-07-19.
- ↑ Voice, Muslim (2022-08-21). "Know Your Sheikh: Professor Ibrahim Ahmad Maqari | The Muslim Voice, Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-07-20.