Jump to content

Ibrahim Hamadtou

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ibrahim Hamadtou
Hamadtou in 2015
Òrọ̀ ẹni
Ọmọorílẹ̀-èdèEgyptian
Ọjọ́ìbí1 Oṣù Keje 1973 (1973-07-01) (ọmọ ọdún 51)
Damietta, Egypt
Sport
Orílẹ̀-èdè Egypt
Erẹ́ìdárayáPara table tennis
Disability classS6
Achievements and titles
Highest world ranking32 (2006)[1]

Ibrahim Al Husseini Hamadtou (ti a bi ni ojo 1 Osu Keje odun 1973), [3] ti a tun mọ si Ibrahim Elhusseiny Hamadtou, jẹ Aṣaju tẹnisi tabili Para ti ara ilu Egypt, ti o gba ọpọlọpọ amin ọla ni opoo ọdun, pẹlu ami-ẹri fadaka ninu idije tẹnisi tabili tabili Para ti Afirika ni ọdun 2011 ati Ọdun 2013.

Hamadtou padanu apa rẹ mejeeji nitori ijamba ọkọ oju irin nigbati o jẹ omo ọdun 10. Ninu ifọrọwanilẹnuwo pẹlu CNN, o sọ pe, “Ni abule wa, ni akoko yẹn nikan la le sere, tẹnisi tabili ati bọọlu afẹsẹgba - iyẹn ni idi ti mo fi le ṣere mejeeji. Ni ti riro bọọlu afẹsẹgba lo yé notori ara mi; lẹhin na ni mo ṣe tẹnisi tabili bi ipenija.” [4]

Hamadtou tun ti gba Irin ọ̀ṣọ́ ìgbóríyìn labẹ Ẹya 6th ti Mohammed bin Rashid Al Maktoum Eye Creative Sports fun ẹka elere idaraya ti o ti ṣaṣeyọri ninu awọn ere idaraya laibikita aini awon nkan pataki (ẹka ti awon eniyan ti o ni iwulo pataki) lẹhin ti o gba ipo keji ati bori ni fadaka Irin ọ̀ṣọ́ ìgbóríyìn ni African Para table tennis Championships ni December 2013. [5]

O ṣe aṣoju Egipiti ni 2016 ati 2020 ere Paralympic Igba ooru ni Rio de Janeiro ati Tokyo .

Hamadtou ti ni iyawo ati pe o jẹ baba olọmọ mẹta. [4]

Àwọn Ìtọ́kasi

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]