Ibrahim Olanrewaju Layode
Ìrísí
Ibrahim Ọláńrewájú Láyọdé (ni a bí ní Ọjọ́ kẹwàá oṣù kọkànlá ọdún 1973)tí ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ OIL jẹ́ òṣèlú ọmọ Yorùbá láti ìlú Badagry, ní ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn méjì tó ń ṣojú ìjọba-ìbílẹ̀ Badagry nílé ìgbìmọ̀ aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó. Sáà ẹ̀kẹ́rin ló ń lórí àléfà gẹ́gẹ́ bí aṣojú ẹkùn kìíní Àgbádárìgì nílé ìgbìmọ̀ aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó.[1] [2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "HON. IBRAHIM O. LAYODE – Lagos State House of Assembly". Lagos State House of Assembly – Above the common standards of excellence. 2016-01-08. Archived from the original on 2020-10-25. Retrieved 2019-11-14.
- ↑ "'Why I want to remain in House of Assembly' – 3rd term legislator, Hon. Olanrewaju Ibrahim Layode (OIL)". Encomium Magazine. 2019-11-14. Retrieved 2019-11-14.