Jump to content

Ichan Kala

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòrán Ichan Kala
Ichan Kala
Agbègbè Àjọgúnbá Àgbáyé ti UNESCO
City walls of Khiva
Ibi tí ó wàKhiva, Ùsbẹ̀kìstán
ÌlànàÀdàkọ:UNESCO WHS type(iii), (iv), (v)
Ìtọ́kasí543
Ìkọsílẹ̀Àdàkọ:If first display both
Ìtóbi rẹ̀37.5 ha (93 acres)
Àwọn ipò41°22′42″N 60°21′50″E / 41.37833°N 60.36389°E / 41.37833; 60.36389Coordinates: 41°22′42″N 60°21′50″E / 41.37833°N 60.36389°E / 41.37833; 60.36389

Ichan Kala (Àdàkọ:Lang-uz) ìlú tí wọ́n mọdi yíká tí ó wà ní Khival ní Ùsbẹ̀kìstán Ìlú yí ti wà lábẹ́ ìnojúwò ati ìdáàbòbò àjọ World Heritage Site láti ọdún 1990. Ìlú àtijọ́ yí ní àwọn ibi ìtàn ní agbáyé tí ó tó àádọ́ta tí wọ́n sì ti wà láti ọ̀rùndún kejìdínlógún tabí kọkàndínlógún sẹ́yìn. Fún àpẹẹrẹ, Mọ́sálásí Djuma ni wọ́n kọ́ ní àárín ọ̀rùndún Kẹwàá tí wọ́n sì tún Mọ́sálásí náà kí ní ọdún 1788 sí 1789.

Ohun tí ó ṣe pàtàkì jùlọ tí ó fijú hàn ní Ichan Kala ni àwọn bíríkì alámọ̀ tí wọ́n fi mọ géètì yíká ìlú náà. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé wọ́n ti fi ìpìlẹ̀ ìlú náà lélẹ̀ ní nkan bí ọ̀rùndún kẹwàá tí ó jẹ́ 10-metre-high (33 ft) tí wọ́n sì fi ìpìlẹ̀ àwọn odi náà lélẹ̀ ní àárín ọ̀rùndún kẹtalélógún tí wọ́n sì tun ṣe láìpẹ́

Àwọn ìtọ́ka sí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Fortresses of Chorasmia Àdàkọ:Tourist attractions in Uzbekistan