Iddi Basajjabalaba Memorial Library

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Iddi Basajjabalaba Memorial Library jẹ́ ilé ìkàwé kan náà ní Kampala International UniversityKansanga, Kampala, orílẹ̀ èdè Uganda, tí wọ́n dá kalẹ̀ ní ọdún 2001. Wọ́n mọ̀ ọ́ tẹ́lẹ̀ sí ilé ìkàwé Kampala International University.[1] Orúkọ rẹ̀ yí padà ní ọdún 2013 ní ìrántí olóògbé Iddi Basajjabalaba, bàbá alága ẹgbẹ́ tí ó ń rí sí ìdarí ilé ìkàwé náà, Hassan Basajjabalaba.[2]

Ìdarí ilé ìkàwé náà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ilé ìkàwé náà wà lábẹ́ ìdarí olùdarí àgbà ilé ìwé náà, Prisca Tibenderana, tí ó ń jábọ̀ fún adarí ètò ẹ̀kọ́ ní Kampala International University.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. ".:: Home | Kampala International University, Uganda". kiu.ac.ug. Retrieved 2021-04-10. 
  2. Correspondent, AGNES KICONCO | PML Daily Staff (2020-05-20). "PML Daily CORONAVIRUS UPDATE: KIU's Hajj Hassan Basajjabalaba donates food to students". PML Daily (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-04-10.