Idris keji ti Morocco

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Idris II
إدريس الثاني
Emir of Morocco
Reign 803–828
Predecessor Idris I
Successor Muhammad ibn Idris
Spouse Hosna bint Sulaiman ben Mohammed al-Najai[1]
Issue
Muhammad ibn Idris
Gannuna bint Idris[2]
Full name
Idris al-Azhar bin Idris bin Abd al-Lah al-Kamil
إدريس الْأَزْهَرَ بْن إدريس بْن عَبْدِ اللهِ الْكَامِلِ
Father Idris I of Morocco
Mother Kenza al-Awrabiya
Born (791-08-00)Oṣù Kẹjọ 791
Volubilis
Died August 828
Fes, Morocco
Burial Fes, Morocco
Religion Islam

Idris bin Idris (Èdè Larubawa: إدريس بن إدريس) ni a tumọsi Idris Keji (Èdè Larubawa: إدريس الثاني) (Óṣu August, Ọdun 1791 – Óṣu August, Ọdun 1828) jẹ ọmọn was the son of Idris Akọkọ, oludari Idrisid dynasty ni Morocco. Idris keji ni a bisi Walīlī óṣu meji lẹ̀yin iku baba rẹ. O dele baba rẹ ni ọdun 1803.

Igbesi Àye Idris Keji[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Idris keji ni a bini óṣu august, ọdun 791, óṣu meji ti Idris akọkọ ku. Iya rẹ jẹ Kenza, ọmọbinrin oloye ti ilu Awraba, Ishaq ibn Mohammed al-Awarbi. Idris kẹji ni a tọ larin awọn ẹya Berber Awraba ti Volubilis. Ni ọdun 803, arakunrin naa di imam moṣalaṣi ti Walila.

Lara awọn oba ti Idrisid, Idris keji lo kawe julọ, lẹyin idari idris keji, afin idrisid fẹ si agbegbe arin odo ti Shalif ati Sus ni iwọ oorun Morocco.

Idris keji ku ni Volubilis ni ọdun 828. Itẹ rẹ wa ni Zawiyya Moulay Idri ni Fez. Itẹ naa ni a tunri nigba idari Marinid Sultan Abd al-Haqq keji (1420–1465) ni 1437, to si di ibi pataki ati mimọ ni ilẹ Fez.

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Glacier, Osire (2016-12-19) (in fr). Femmes politiques au Maroc d'hier à aujourd'hui: La résistance et le pouvoir au féminin. Tarik Editions. ISBN 978-9954-419-82-3. https://books.google.com/books?id=N7y2DQAAQBAJ&newbks=0&printsec=frontcover&pg=PT18&dq=Celuici+a+assum%C3%A9+le+pouvoir+vers+804,+%C3%A0+l'%C3%A2ge+de+onze+ans.+...+D%C3%A8s+lors,+le+jeune+sultan+aurait+eu+deux+conseill%C3%A8res+loyales,+%C3%A0+savoir+sa+m%C3%A8re+et+sa+conjointe,+Hosna+bent+Sola%C3%AFmane+ben+Mohammed+anNaja%C3%AE&hl=en. "Kenza would also advise Idris II in his personal affairs. Besides, it was she who chose a wife for him. From then on, the young sultan would have had two royal advisers, namely his mother and his spouse, Hosna bent Solaïmane ben Mohammed anNajaï" 
  2. Soufi, Fouad (1998-04-30). "Famille, femmes, histoire : notes pour une recherche" (in fr). Insaniyat / إنسانيات. Revue algérienne d'anthropologie et de sciences sociales (4): 109–118. doi:10.4000/insaniyat.11709. ISSN 1111-2050. https://journals.openedition.org/insaniyat/11709.