Idrissa Adam

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Justin Gatlin àti Idrissa Adam ní àkókò àwọn eré-ìdíre àgbáyé ti ọdún 2013 ní ìlú Moscow.

Idrissa Adam (ti a bi ni ọjọ kejidinlọgbọn osu kejila ọdun 1984) [1] je elere-ije orile-ede Cameroon ti o dije ninu 100 Mita and 200 mita

Ijade agbaye akọkọ rẹ wa ninu idije ere idaraya Junior ti Afirika ni ọdun 2003, nibiti o ti gbe ipo karun ni 100mita.  O gba ami-eye akọkọ ipele continental rẹ ni ọdun ti ọ tele, o gba ami- eyẹ idẹ ni 4 × 100 mita ni ere idaraya Afirika ni ọdun 2004 ni ẹgbẹ kanna pẹlu Joseph Batangdon . O jẹ ọdun mẹrin ki o to gba ami-eye pataki miiran: ni ere idaraya Afirika ni ọdun 2008 oun ati Batangdon tun gba idẹ pada fun Cameroon. O gbe ipo kẹrin ni ere idaraya yẹn ni 2009 Jeux de la Francophonie . [2]

O ṣe aṣoju fun orilẹ-ede Cameroon ni 100 ati 200 m ninu àwọn ìdíje mejeeji wonyi 2010 African Championships in Athletics ati 2010 Commonwealth Games, sugbon ko ni ilọsiwaju kọja ipele akoko. O fi ara rẹ mulẹ bi olusare ni 2011 Gbogbo awon ere idaraya Afirika, nibiti o ti ṣe itan titun bale fun orilẹ-ede Kamẹru pelu 10.14 iṣẹju-aaya ni 100 m ologbele-ipari (o tun wa pari si ipo kẹfa) ati pe o jẹ olubori iyalẹnu ti 200 m goolu medal saaju Ben Youssef Meité . [3]

Awọn itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Idrissa Adam Archived 2017-07-11 at the Wayback Machine.. All-Athletics. Retrieved 17 September 2011.
  2. Vazel, P-J (3 October 2009). Berrabah’s 8.40m Moroccan Long Jump record highlights – Francophone Games, Day 2. IAAF. Retrieved 17 September 2011.
  3. All-Africa Games – Jeux Africains, Maputo (Mozambique) 11-15/9. Africa Athle. Retrieved 17 September 2011.

Ita ìjápọ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Footer All-Africa Champions 200 m Men