Ifeoma Aggrey-Fynn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ifeoma Aggrey-Fynn
Fáìlì:Ifeoma Aggrey-Fynn.jpg
Ọjọ́ìbí8 June 1980
Aláìsí2 June 2015 (aged 34)
Nigeria
Cause of deathMurder caused by gunshot wounds
Orúkọ mírànIphie
Iléẹ̀kọ́ gígaAbia State University
Iṣẹ́Radio and television personality
EmployerSilverbird Communications

Ifeoma Iphie Aggrey-Fynn (8 June 1980 – 2 June 2015), known to most simply as Iphie, was a Ghanaian-Nigerian media personality, writer and public speaker.[1]

Ìgbé ayé àti Ètò Ẹ̀kọ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Baba tí ó bí Aggrey-Flynn jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Ghana nígbà tí ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Wọ́n bí sílu Nàìjíríà, ó sí kẹ́kọ̀ọ́ ní orílé èdè Nàìjíríà. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyẹ̀ ní Fásiti tí ó wà ní Ìpínlè Ábíá ní orílé èdè Nàìjíríà ní bí tí ó gboyẹ̀ nínú Ẹ̀kọ́ Lìǹgúsítíkí àti Communication.[1]

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Iṣẹ́ Aggrey-Fynn ní tí ó jẹ́ igbohunsafefe bẹ̀rẹ̀ bí olùtajà lórí èrò amóhùnmáwòrán TV ní ọdún 2003. Lẹ́yìn tí ó darapọ̀ mọ́ wọn ní ilé iṣé Ìbáẹnisọ̀rọ̀ Silverbird ní ọdún 2009, ní ó lọ sí ilé iṣẹ́ tí orí rédíò Rhythm 95.7 FM àti Silverbird Television ní Awka. Níbè ni ó tí ń ṣe sọ̀rọ̀ sọ̀rọ̀ lórí rédíò àti àwọn ètò lórí tẹlifísàn tí àwọn bí Rhythm & Soul, Gospel Vibes and E-Merge kí ó tó padà lọsí ilé iṣé Rhythm 93.7 FM ní Port Harcourt. [2][3][4]

Ó jẹ́ agbẹnusọ àti agbàlejò fún ètò Miss Niger Delta beauty pageant ní ẹ̀ẹ̀mẹta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀.[5]

Ikú Olóògbé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Aggrey-Fynn lọsí Ábíá lati lọ kí àwọn òbí rẹ̀, ojú ọnà port Harcourt tí ó ń gbà bọ̀ nínú ọkọ̀ akérò ní àwọn Ọlọ́sà tí dènà tí wọn sì ṣe jàǹbá fún wọn.[6][7][8] As the driver was driving, the gunmen opened fire on the vehicle.[9] Aggrey-Fynn was hit by bullets and died of wounds.[10][11]

Àwọn mìíràn pé ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ ní ó ń wa ọkọ̀ bọ́ wásí ilé ní ọjọ́ Kejì osù kẹfà, ọdún 2015. Níbi tí ó tí lọsí Ábíá láti lọ rí àwọn òbí àti mọ̀lẹ́bí rẹ, wọn fẹ́ẹ̀ dé ibè ní àwọn Ọlọ́sà dá wọn lọnà, tí wọn sì yin ìbon nígbà tí ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ gbìyànjú láti wakọ̀. Ìṣẹlẹ yìí sẹlẹ̀ ní ọwọ́ aago méje ìrọ̀lẹ́ ní agbègbè ilé Aggrey-Fynn.Àdàkọ:Cn ìbọn tí àwon ọlọ́sà yín ló mú kí Aggrey-Fynn wà ní agbára ẹjẹ, ti wọn sì gbé ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ lọ. Àwọn olùgbé agbègbè tí ìṣẹ̀lẹ̀ yìí tí ṣẹlẹ̀ ní wọ́n gbé Aggrey-Fynn lọsí ilé ìwòsan níbi tí wọn tí pé ó tí dì àìsí kí ó tó dé ilé ìwòsan.[12]

E wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "Why I love Nigerian music – Ifeoma Aggrey-Fynn". The Sun. 12 March 2014. http://sunnewsonline.com/new/?p=55896. 
  2. "Rhythm 93.7 OAP Iphie shot dead". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-06-03. Retrieved 2022-05-27. 
  3. Elites, The (2015-06-03). "Rhythm 93.7FM AOP, Iphie Shot Dead". The Elites Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-28. 
  4. Helen, Ajomole (2015-06-03). "SO SAD: Popular OAP Shot Dead By Robbers". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-28. 
  5. "Ifeoma Aggrey-Fynn biography, net worth, age, family, contact & picture". www.manpower.com.ng. Retrieved 2020-05-27. 
  6. Abiaziem, Chinyere (4 June 2015). "Robbers Kill Another Silverbird Staff". Daily Independent. http://dailyindependentnig.com/2015/06/robbers-kill-another-silverbird-staff/. 
  7. Adebayo, Tireni (2015-06-03). "How popular Rhytm[sic] FM OAP, Ifeoma 'Iphie' Aggrey-Fynn was shot dead by armed robbers". Kemi Filani News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-27. 
  8. Latestnigeriannews. "OAP Ifeoma Aggrey-fyn Shot Dead By Kidnappers". Latest Nigerian News (in English). Retrieved 2022-05-28. 
  9. "Ghanaian female radio presenter in Nigeria shot dead". Theinfong (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-06-05. Retrieved 2022-05-28. 
  10. "Rhythm 93.7 FM On-Air-Personality, Iphie, Shot Dead In Port Harcourt". Daily Independent. 3 June 2015. http://dailyindependentnig.com/2015/06/rhythm-93-7-fm-air-personality-iphie-shot-dead-port-harcourt/. 
  11. Jacobs, Anike (3 June 2015). "Rhythm FM presenter shot dead in Port Harcourt". YNaija. Archived from the original on 3 June 2015. https://web.archive.org/web/20150603204247/http://live.ynaija.com/ifeoma-iphie-aggrey-fynn-rhythm-93-7-fm-port-harcourt-shot-dead/. 
  12. Ebiri, Kelvin (5 June 2015). "Iphie's voice silenced forever". The Guardian (Port Harcourt). http://www.ngrguardiannews.com/2015/06/iphies-voice-silenced-forever/. 

External links[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Authority control