Ifeoma Mbanugo
Ìrísí
Òrọ̀ ẹni | |
---|---|
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọjọ́ìbí | 3 Oṣù Kẹta 1952 |
Sport | |
Erẹ́ìdárayá | Long-distance running |
Event(s) | Marathon |
Ifeoma Mbanugo (jẹ́ ọmọ ọjọ́ kẹta oṣù kẹta ọdún 1952) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ - èdè Nàìjíríà tí ó sáré eré gún gùn. Ó díje nínú eré ìdíje ní àwọn Olimpiki ti Ọdún 1984.