Jump to content

Igbó òkè Cameroon

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Igbó òkè Cameroon jẹ́ àwọn igbó tí ó wà ní àwọn òkè Gulf of Guinea tí ó sì pàlà láàrin orílẹ̀-èdè Cameroon àti Nàìjíríà. Agbègbè ibè kún fún àwọn igi àti koríko, àwọn igi ibè ń díkù si, àwọn koríko rẹ̀ ń sì pò si nítorí iṣẹ́ àgbẹ̀ tí wọ́n ń ṣe níbẹ̀.[1][2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Map of Ecoregions 2017" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Resolve. Retrieved August 20, 2021. 
  2. "Cameroonian Highlands forests" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). The Encyclopedia of Earth. Retrieved August 20, 2021.