Igbó òkè Orashi
Ìrísí
Igbó òkè Urashi jẹ́ igbó kan lábẹ́ àbò ìjọba ní Ìpínlẹ̀ Rivers ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà níbi òkè tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Odò Urashi, ní abúlé Ikodi ti Ahoada West. Igbó náà gba ilẹ̀ tí ó tó 25,165 ha (97.163 sq mi). Àjọ Ramsar Convention ká mọ́ àwọn igbó tí ó ti ó ṣe pàtàkì ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹrin ọdún 2008.[1]
Ìgbà ní ibè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìgbà igbó òkè Urashi ní ìgbà òjò àti ìgbà ẹ̀rùn, ìgbà òjò ma ń wá láti oṣù kẹta títí di oṣù kọkànlá, ìgbà ẹ̀rùn sì ma ń wá láti oṣù Kejìlá sí oṣù kejì. Omi láti odò Urashi ma ń ya wo igbó náà láti oṣù kẹsàn-án sí oṣù kọkànlá.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Upper Urashi Forests in Nigeria". wdpa.org. Retrieved 14 July 2017.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "The Annotated Ramsar List of Wetlands of International Importance". Ramsar.org. Retrieved 14 July 2017.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]