Ijan Ekiti
Ìrísí
Ìjàn Èkìtì [1] jẹ́ ìlú ńlá kan tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkìtì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Iye àwọn olùgbé ibẹ̀ jẹ́ ọmọ Yorùbá àtàtà tí wọ́n sì yan iṣẹ́ àgbẹ̀ láàyò gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ òòjọ́ wọn tí wọ́n sì ń gbin àwọn ohun ọ̀gbìn bíi: Ìrẹsì ,Ẹ̀gẹ́ , Iṣu , tábà, òwú àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, bá kan náà ni wọ́n yan iṣẹ́ aṣọ híhun láàyò. Gẹ́gẹ́ bí ètò ìkànìyàn ọdún 2004 ṣe fi léde, iye àwọn olùgbé ìlú Ìjàn jẹ́ 46,749 lápapọ̀. Orúkọ adarí tàbí Ọba wọn ní Ìlú ìjàn Èkìtì ni Oníjàn ti Ìjàn Èkìtì[2]
Àwọn ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ijan Ekiti : historical highlights in SearchWorks catalog". SearchWorks catalog. 2021-06-19. Retrieved 2021-06-26.
- ↑ "IJAN EKITI". IJAN EKITI. 2011-04-12. Retrieved 2021-06-26.