Ọba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Adé ati ọ̀pá ọba je awon ami-idamo agbara oba kan

Ọba je ọkùnrin to n solori ilu, ile tabi orile-ede nito ri pe o jogun ipo yi. O le je taara lati inu ebi re tabi nitoripe ebi re lokan. Opo awon ni ile Yoruba lori bayi. Won ni awon afọbajẹ ti won gbimo ibo ni tabi inu ebi wo ni oba to kan yio ti wa.[1] Ni Europe oba n je lati inu ebi kanna. Yio gori ite taara lati odo bàbá tabi ìyá re.

Iyawo oba ni a n pe ni ayaba tabi ayaoba. Ni Europe obìnrin yi le gun ori ite ti oba ba ku, eyi ko je be ni ile Yoruba nibi ti obinrin ko le di oba.

Ti olori orile-ede kan ba je oba a n pe iru ijoba yi ni idobaje, ti oba na si n je adobaje.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]