Bàbá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Bàbá pelu ọmọ.

Bàbá ni ọbí to je ọkùnrin eyan kan. Opolopo awon ẹranko ati eniyan ni won ni ìyá ati baba to bi won.

Ni awon àṣà miran won pe baba ni okunrin to dagba tabi to nipo ju onitoun lo. Bakanna awon elesin Kristiani n pe ọlọ́run ni baba: "Baba wa ti n be ni orun"Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]