Ìyá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Ìyá àti ọmọ rẹ̀

Ìyá (màmá tabi mọ̀nmọ́n) ni òbí to je obìnrin eyan kan. Iya ati bàbá je obi fun ọmọ tabi eniyan kan. Ni opolopo iya lo omo fun ra re, nigba miran o le gba omo elomiran bi omo re tabi ki o gba omo elomiran bi.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]