Jump to content

Ijeoma Uchegbu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ijeoma Uchegbu
Ijeoma Uchegbu at the Oxford Union Science Debate 2018
Ilé-ẹ̀kọ́University of Strathclyde
University College London
Ibi ẹ̀kọ́University of Benin
University of Lagos
University of London
Ó gbajúmọ̀ fúnNanoparticle drug delivery

Ijeoma Uchegbu jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ti ẹ̀kọ́ nípa ìmọ̀-oògùn ní University College London, níbi tí ó ti dipò igbákejì Ààrẹ mú fún ilẹ̀ Adúláwọ̀ àti ààrin-gbùngùn. Ó jẹ́ Nigerian-Britih. Òun ni olóri oníṣẹ́ sáyẹ̀ǹsì ti Nanomerics, èyí tí ń ṣe ilé-iṣẹ́ tó ń ṣe oògùn láti wá ojútùú sí omi tí ò mọ́. Òun sì ni Gómìnà Wellcome, èyí tí ń ṣe ilé-iṣẹ́ oògùn tó ń ṣe ìwádìí, tó sì ń fi inú-rere hàn fún àwùjọ.[1] Uchegbu ni a tún mọ̀ fún iṣẹ́ ribiribi rẹ̀ lóri sáyẹ̀ǹsì nínú science public engagement àti equality and diversity nínú Science, Technology, Engineering àti Mathematics (STEM).[2][3]

Àtòjọ ìwé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • 2000 Synthetic Surfactant Vesicles: Niosomes and Other Non-phospholipid Vesicular Systems: 11 (Drug Targeting and Delivery)[4]
  • 2006 Polymers in Drug Delivery[5]
  • 2013 Fundamentals of Pharmaceutical Nanoscience[6]

Àtòjọ àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Ijeoma Uchegbu - Google Scholar Citations". scholar.google.co.uk. Retrieved 2019-02-28. 
  2. "Role models | Women's Engineering Society". wes.org.uk. Archived from the original on 2019-03-01. Retrieved 2019-02-28.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. UCL (2018-07-12). "Deans pledge to further race equality at UCL". UCL Human Resources (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-02-28. 
  4. Uchegbu, L. F. (2000-02-01) (in English). Synthetic Surfactant Vesicles: Niosomes and Other Non-Phospholipid Vesicular Systems (1st ed.). Amsterdam: CRC Press. ISBN 9789058230119. 
  5. Uchegbu, Ijeoma F., ed (2006-05-19) (in English). Polymers in Drug Delivery (1st ed.). Boca Raton, Fla.: CRC Press. ISBN 9780849325335. 
  6. Uchegbu, Ijeoma F., ed (2013-12-09) (in English). Fundamentals of Pharmaceutical Nanoscience (2013 ed.). New York; Heidelberg: Springer. ISBN 9781461491637. 
  7. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :2
  8. "2012 RPS award winners announced". Pharmaceutical Journal. https://www.pharmaceutical-journal.com/news-and-analysis/2012-rps-award-winners-announced/11106243.article. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  9. "Academy of Pharmaceutical Sciences Eminent Fellows". APSGB. Archived from the original on 2018-10-21. Retrieved 2018-10-21.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  10. "College of Fellows Award Recipients". controlledreleasesociety.org. Archived from the original on 2018-10-22. Retrieved 2018-10-21. 
  11. UCL (2016-11-09). "Professor Ijeoma Uchegbu wins Innovative Science Award". UCL School of Pharmacy. Retrieved 2018-10-21. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]