Ikọ́

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ikọ́ jẹ́ ọ̀nà gbígbé atẹ́gùn jáde pẹ̀lú agbára láti ọ̀nà ọ̀fun kí a lè fọ ọ̀nà ọ̀fun náà mọ́ kúrò lọ́wọ́ ìdọ̀tí tí ó sá pamọ́ síbẹ̀. Ikọ́ wíwú lè jẹ́ lẹ́ẹ̀kan tàbí léra-léra tí yóò sì mú kẹ̀lẹ̀bẹ̀ dání.[1] Wíwúkọ́ léra-léra lè túmọ̀ sí wípé àìsàn tàbí àrùn kan wà ní àgọ́ ara nítorí wípé púpọ̀ lára àwọn àrùn àgọ́ ara ni a lè tàn kálẹ̀ tàbí pin fún ẹlòmíràn

Ṣíṣe ìtọ́jú ikọ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ṣíṣe ìtọ́jú ikọ́ nííṣe pẹ̀lú wíwádí ohun tí ó fa ikọ́ fúnra rẹ̀, bí a bá ti mọ̀ọ́n, ìtọ́jú rẹ̀ yóò yá kánkán.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Prevalence, pathogenesis, and causes of chronic cough". Lancet 371 (9621): 1364–74. April 2008. doi:10.1016/S0140-6736(08)60595-4. PMID 18424325. 
  2. "Management of chronic cough". Lancet 371 (9621): 1375–84. April 2008. doi:10.1016/S0140-6736(08)60596-6. PMID 18424326.