Ikechukwu Kalu
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Ikechukwu Kalu | ||
Ọjọ́ ìbí | 18 Oṣù Kẹrin 1984 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Kaduna, Nigeria | ||
Ìga | 1.73 m (5 ft 8 in) | ||
Playing position | Striker, Attacking midfielder | ||
Youth career | |||
1998–2002 | Jasper United | ||
2002–2003 | U.C. Sampdoria | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2003–2007 | A.C. Milan | 8 | (2) |
2003–2004 | → Aurora Pro Patria (loan) | 26 | (4) |
2004–2005 | → Pisa Calcio (loan) | 26 | (7) |
2005–2007 | → FC Chiasso | 48 | (28) |
2007–2008 | → U.C. Sampdoria | 25 | (10) |
2008–2010 | AC Bellinzona | 21 | (11) |
2010–2011 | FC Chiasso | 19 | (9) |
2012 | Kuopion Palloseura | 22 | (9) |
2013 | FF Jaro | 21 | (8) |
2013 | AC Bellinzona | 20 | (10) |
2014 | Teuta Durrës | 10 | (5) |
2014–2015 | Singhtarua F.C. | 13 | (2) |
National team | |||
2003 | Nigeria | ||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Ikechukwu Kalu ti won bi ni ojo kejidinlogun, osu kerin ni 1984 je agbaboolu Naijiria to gba boolu gege bi Olutayo. Oruko e Ikechukwu, tunmo si "agbara oluwa”.[1]
Ise re bii a-gba-boolu
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]O bere ise e ni Jasper United ni Nàìjíríà. O tewo bowe pelu U.C. Sampdoria ni summer 2002. Leyin to gba fun akoko kan ni Genoa, A.C. tewo bowe pelu ni summer 2003 pelu apapo-nini fun €1 million, ati o ri Luca Antonini sun si odi keji ni apapo-nini idaradura (fun €2 million),[2]
won ya lo si Pisa and Chiasson. O gba goolu mejidinlogbon in 44 games ni akoko meji ni Swiss second division, which saw Sampdoria recall him in summer 2007. He made his Serie A debut on 10 November 2007 against Empoli F.C.
Ni osu kefa 2008, Sampdoria gbe Kalu pada lati Milan fun €250,000 ati ni akoko yii tewo bowe pelu Paolo Sammarco fun €2.5 million.[3] Igba to tun ya, won ta a fun awon ara Swiss fun, egbe a-gba-boolu AC Bellinzona fun€400,000.[4]
Awon Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ikechukwu - Nigerian.Name". www.nigerian.name (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-05-14.
- ↑ AC Milan Spa 2006 Annual Report Archived 2011-04-25 at WebCite Àdàkọ:In lang
- ↑ "AC Milan Group 2008 Annual Report" (PDF). AC Milan (in Italian). ca. April 2009. Archived from the original (PDF) on 14 May 2013. Retrieved 11 June 2011. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help); Check date values in:|date=
(help) - ↑ U.C. Sampdoria SpA bilancio (financial report and accounts) on 31 December 2008 Àdàkọ:In lang, PDF purchased from Italian CCIAA