Jump to content

Ikechukwu Uche

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ikechukwu Uche

Uche gẹ́gẹ́ bi agbábọ́ọ̀lù Getafe
Personal information
OrúkọIkechukwu Uche
Ọjọ́ ìbí5 Oṣù Kínní 1984 (1984-01-05) (ọmọ ọdún 40)
Ibi ọjọ́ibíAba, Nigeria
Ìga1.71 m (5 ft 7 in)
Playing positionStriker
Youth career
Amanze United
2000–2001Iwuanyanwo Nationale
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2002–2003Racing Ferrol28(2)
2003–2007Recreativo133(50)
2007–2009Getafe55(11)
2009–2011Zaragoza18(1)
2011–2015Villarreal85(33)
2011–2012Granada (loan)34(3)
2015–2016UANL0(0)
2016Málaga (loan)3(0)
2016–2019Gimnàstic75(21)
National team
2007–2014Nigeria46(19)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 9 June 2019.
† Appearances (Goals).

Ikechukwu Uche (Wọ́n bi ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kìíní (ṣẹrẹ), ọdún 1984) jẹ́ Agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà tó gbá bọ́ọ̀lù ní ìpò iwájú (Sítíráíkà)

tí wọ́n mọ̀ fún eré-ìtakìtì fún ayẹyẹ òpin bọ́ọ̀lù rẹ̀,[1]

Uche gba bọọlu fun Naijiria ni Africa Cup of Nations.