Iko

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ọmọ tí ó ń wúkọ́ nítorí àìsàn whooping cough

Ikọ́ jẹ́ ohun tí ó máa ń wáyé láti mú ikun àti ìdọ́tí bíi eruku tàbí èéfín kúrò ní àyà wa. Ikọ́ fún ra rẹ̀ kìí se àìsàn ṣùgbọ́n wíwú Ikọ́ léraléra lè jẹ́ àmì wípé àìsàn wà lára. Ikọ́ jẹ́ ọ̀kan lára nkan tí ènìyàn ó ní agbára lé lórí, kódà bí ènìyàn kò bá fẹ́ wúkọ́, bí ìdọ́tí tàbí àìtó bá ti wọ ọ̀nà ofun tàbí ẹ̀dọ̀fóró, ikó ma wáyé láti tíì síta, ènìyàn o le dá ikó dúró[1]

Ikọ́ wà lára àwọn ọ̀nà tí ara ń fi dàbọ̀ bo ara rẹ̀. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ikọ́ jẹ́ nkan tí ènìyàn kò lágbára lórí, ènìyàn fún ra rẹ̀ le wúkọ́ láti mú ìkan kúrò ní ọ̀nà ọ̀fun fúnra rẹ̀. Ọ̀pọ̀lopọ̀ àrùn tí ó ń fa ikọ́ ni ó máa ń lọ fúnra rẹ̀ ní àárín ọ̀ṣẹ̀ mẹ́ta tí wọn kò sì nílò ìtójú.[2][3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Association, American Lung (2022-11-21). "Learn About Cough". American Lung Association. Retrieved 2023-02-09. 
  2. pennmedicine.org https://www.pennmedicine.org/for-patients-and-visitors/patient-information/conditions-treated-a-to-z/cough. Retrieved 2023-02-09.  Missing or empty |title= (help)
  3. "Symptoms and causes". Mayo Clinic. 2019-07-09. Retrieved 2023-02-09.