Ilé-Ìṣọ́ Bábẹ́lì
Ìrísí
Kini Ile-Iso Babeli?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ilé-Ìṣọ́ Bábẹ́lì ti je ile iso ti awon eniyan ni ibere ti ayé won ti ko. Won ti fe pé ile-iso won ma lo si orun, tabi ijoba orun. Nigba naa, nigba Oluwa-Olorun ti ri pé won ti je papo ati won le se gbogbo ohun ti je ni okan won lati se, o ti sokale ati o ti ruju ati fun won opolopo ede miiran. Nigba naa, awon eniyan ti da duro lati ko ile-iso yii ati won si jade ati tankale lori gbogbo ayé.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |