Ilé ìkàwé Òrílẹ̀ èdè Democratic Republic of Congo
Ìrísí
Ìlé Ìkàwé orílẹ̀ èdè Democratic Republic of Congo (Faransé: Bibliothèque Nationale de la République démocratique du Congo) jẹ́ ilé ìkàwé tí ó wà ní Kinshasa tí wọ́n sì dá kalẹ̀ ní ọdún 1974 gẹ́gẹ́ bi ọ́fícì ní ẹ̀ka ìjọba fún àṣà. Ní ọdún 1989, ó gba òmìnira láti di ilé ìkàwé.[1]
Ní ọdún 2009, ilé ìkàwé náà gba owó tí ó tó $15 million ní ọwọ́ Model United Nations of the University of Chicago àtí UNESCO láti tún ilé ìkàwé náà ṣe, kó àwọn òṣìṣẹ́ ìbẹ̀ àti láti ra àwọn ìwé.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Marcel, Lajeunesse; Henri Sene (December 2004). "Legislation for library and information services in French-speaking Africa revisited". The International Information & Library Review 36 (4): 367–380. doi:10.1016/j.iilr.2004.03.002.
- ↑ "DR Congo: National Library-MONUC contributes to preserve "the memory of the nation"". UN Organization Mission in the Democratic Republic of Congo. Retrieved 9 November 2013.