Ile-iwe giga
Ìrísí
Ile-iwe giga tí a tún mò sí ilé-èkó giga jé ile-iwe tí a ti ún keko(àti keko gboye) léyìn ilé-ìwé sekondiri [1]. Gbòógì orisi meta ilé-èkó ni ówà ní Nàìjíríà, ilé-èkó yunifásitì, polytechnics àti college ti education [2]. Yunifásitì fún akeko gboyè ní oyè básélò(Bachelor degree) [3], polytechnic fún akeko gboyè ní oyè diploma àti higher diploma [4], college ti education sì ún fún akeko gboye ní NCE(National certificate of education) [4].
Kikeko gboyè ní ilé-ìwé giga ma ún saba jé nkan àmúye fún òpòlopò isé, ní òpòlopò ìgbà, àwon tí o gbá oyè èkó ilé ìwé giga ma ún gbà èrè ti o pò ní isé ju awon tí ko lò ile-iwe giga lo [5]
Àwon Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Postsecondary Education Definition and Meaning". Top Hat. 2020-08-12. Retrieved 2022-03-03.
- ↑ Elizabeth, Kemisola (2000-01-01). "List of The NUC Recognized Tertiary Institutions in Nigeria.". shopinverse. Archived from the original on 2022-03-03. Retrieved 2022-03-03.
- ↑ "Undergraduate courses". The University of Sydney. 2022-02-25. Retrieved 2022-03-03.
- ↑ 4.0 4.1 "BSC, HND, OND, NCE, A'level: What are the Differences?". School Contents. 2019-11-14. Retrieved 2022-03-03.
- ↑ "The benefits of higher education". Allison Academy. 2021-07-08. Retrieved 2022-03-03.