Jump to content

Ile Ẹrù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ilé Ẹrù

Ilé Ẹrù ni ó jẹ́ ilé tí wọ́n ma ń kó àwọn ǹkan oko sí nígbà tí wọ́n bá dé láti oko sí. Wọ́n ma ń lo àwọn ilé ẹrù fún oríṣiríṣi bíi: Ibùgbé àwọn ẹranko, ibùgbé ẹṣin tàbí ilé óunjẹ.[1].

Awọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Allen G. Noble, Traditional Buildings: A Global Survey of Structural Forms and Cultural Functions (New York: Tauris, 2007), 30.