Ilesanmi Adesida
Ìrísí
Ilésanmí Adéṣidà | |
---|---|
Ìbí | 1949 Ifon, Ìpínlẹ̀ Oǹdó, Nàìjíríà |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Amẹ́ríkà |
Pápá | Electrical engineering |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Illinois at Urbana |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of California, Berkeley |
Ó gbajúmọ̀ fún | Material science |
Ilésanmí Adéṣidà tí wọ́n bí ọdún 1949 jẹ́ onímọ̀ sáyẹ́nsì ọmọ bíbí ilẹ̀ Yoruba ará orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |