Ime Bishop Umoh
Ime Bishop | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ime Bishop Umoh 15 July 1981 Nsit Ibom, Akwa Ibom State |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | Okon Lagos |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University Of Uyo |
Iṣẹ́ | actor, comedian |
Olólùfẹ́ | Àdàkọ:Married |
Àwọn ọmọ | (2) |
Ime Bishop, tí wọ́n tún pè níOkon Lagos tàbí Udo Yes, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé , aláwàdà ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Nigeria.
ìbẹ̀ré ayé àti iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ime jẹ́ ọmọ bíbí agbègbè Nsit Ibom àti ẹ̀yà Ìbíòbíó láti Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì Uyo níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ẹ̀kọ́ philosophy. Ó ti bẹ̀rẹ̀ síṣe eré orí-ìtàgé láti ìgbà tí ó yo wà ní ọmọdé, lẹ́yìn tí ó ti dara pọ̀ mọ́ Nollywood ó ti kópa nínú eré tí ó ti tó ọgọ́rùn ún. Eré tí ó gbe ìràwọ rẹ̀ jáde ni Uyai, eré tí ọ̀gbẹ́ni Emem Isong gbé jáde ní ọdún 2008. [1][2]
Ìfọwọ́ sí rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìyànsípò ìṣèlú rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n yan Ime sí ipò olùdámọ̀ràn pàtàkì sí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom, ìyẹn Udom Gabriel Emmanuel lórí ìlanilọ́yẹ̀ fún ará ìlú.[4]
Àwọn amì-ẹ̀yẹ àti ìfisọ́rí rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Ayẹyẹ | Ẹ̀bùn | Ẹni tí ó gbàá | Èsì |
---|---|---|---|---|
2012 | 2012 Best of Nollywood Awards | Comedy Movie of the year | Okon lagos 2 | Gbàá |
2013 | 2013 Best of Nollywood Awards | Comedy of the year | Okon goes to school | Gbàá |
2013 | 2013 Nollywood Movies Awards | Best Actor in Supporting Role | Udeme Mmi | Gbàá |
2014 | 2014 Best of Nollywood Awards | Best Comedy of the year | I come lagos | Gbàá |
2016 | 2016 Nigeria Teen Choice Awards | Comic Actor of the year(English) | [5] | Wọ́n pèé |
2016 | 2016 Africa Magic Viewers Choice Awards | Best Actor in a comedy | Caught in the Act | Wọ́n pèé |
2017 | 2017 Africa Magic Viewers Choice Awards | Best Actor In Comedy | The Boss is Mine | Gbàá |
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àkọ́lé | Ọdún |
---|---|
Uyai | 2008 |
Edikan | 2009 |
Silent Scandals | 2009 |
The Head Office | 2011 |
Vulcanizer | 2011 |
Okon Lagos | 2011 |
Udeme mmi | 2012 |
Okon goes to school | 2012 |
Sak Sio | 2012 |
Jump and pass | 2013 |
The place | 2013 |
The champion | |
Okon the driver | 2014 |
Okon on the run | 2014 |
Okon and Jennifer | 2015 |
Udo Facebook | 2015 |
The Boss Is Mine | 2016 |
Lost In London | 2017 |
Unroyal | 2020 |
Ime kópa nínú fọ́nrán fídíò kan tí wọ́n oè ní Pregnant Man lẹ́yìn tí ìsémọ́lé ajàkálẹ̀ àrùn COVID-9 rọlẹ̀ díẹ̀.[6]
Ẹ tún wo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.pulse.ng/entertainment/movies/ime-bishop-umoh-10-things-you-should-know-about-nollywood-actor/hly72v0
- ↑ https://www.vanguardngr.com/2012/12/the-quality-of-comedy-in-me-can-be-bottled-sold-bishop-umoh/
- ↑ "Glo signs on 28 ambassadors; Mama G, Wizkid, AY, P-Square , Korede Bello top list". Vanguard (Nigeria). 1 July 2015. https://www.vanguardngr.com/2015/07/glo-signs-on-28-ambassadors-mama-g-wizkid-ay-p-square-korede-bello-top-list/. Retrieved 18 May 2020.
- ↑ "Nollywood actor appointed SA to Akwa ibom governor". Thenewsnigeria. Retrieved 10 October 2016.
- ↑ "2016 NTCA Awards". 2 June 2016.
- ↑ https://m.youtube.com/watch?v=IoIDcWSp89k