In-Young Ahn
In-Young Ahn | |
---|---|
Ahn ní King Sejong Station | |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | South Korean |
Pápá | Antarctic Marine Ecology |
Ilé-ẹ̀kọ́ | South Korean Polar Research Institute (KOPRI) |
Ibi ẹ̀kọ́ | State University of New York at Stony Brook |
Ó gbajúmọ̀ fún | Obìnrin àkọ́kọ́ ọmọ Korea tí ó maa kọ́kọ́ dé Antarctica obìnrin àkọ́kọ́ ọmọ Asia tí ó maa ṣe olórí ibùdó Antarctic |
In-Young Ahn jẹ́ onímọ̀ ìjínlẹ̀ ọmọ orílẹ̀ èdè South Korea. Ó jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ ọmọ Korea tí ó maa kọ́kọ́ dé Antarctica, ó sì jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ ọmọ Asia tí ó maa ṣe olórí ibùdó Antarctic (King Sejong Station).[1][2][3] Ó jẹ́ onímọ̀ ìbáṣepọ̀ oun ẹlẹ́mì ìsàlẹ̀ omi àti agègbè wọn, ó sì ń ṣiṣẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ gẹ́gẹ́ bíi ọ̀gá onímọ̀ ìjìnlẹ̀ ìwádí fún Korea Polar Research Institute.[4][5]
Ìgbà èwe àti ẹ̀kọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ahn yege nínú ẹ̀kọ́ lati Seoul National University ní ọdún 1982 (nínú Biological Oceanography) ó sì gba PhD rẹ̀ nínú Coastal Oceanography lati State University of New York ní Stony Brook ní ọdún 1990. Ahn bẹ̀rẹ̀ ìwádí rẹ̀ ní Korean Polar Research Institute (KOPRI) ní Ọjọ́ kínín Oṣù keje Odún 1991.[2]
Career and impact
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ahn wá ní ìdí ètò ìṣàmójútó àyíka ní King Sejong Station lati odún 1996 sí 2011, ó sì ṣe ìwádi lati gba ìjìnlẹ̀ dátà tí ó wúlò yíyàn Antarctic Specially Protected Area (ASPA #171) nítòsí ibùdó Korea.
Àwọn iṣẹ́ rẹ̀ tí a yàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ahn, In-Young, et al. "First record of massive blooming of benthic diatoms and their association with megabenthic filter feeders on the shallow seafloor of an Antarctic fjord: Does glacier melting fuel the bloom?" Ocean Science Journal 51. 2 (2016): 273–279.
- HW Moon, WMRW Hussin, HC Kim, In-Young Ahn*. "The Impacts of climate change on Antarctic nearshore mega-epifaunal benthic assemblages in a glacial fjord on King George Island: Responses and implications." Ecological Indicators 57 (2015): 280–292.
- Ahn, In-Young, et al. "Growth and seasonal energetics of the Antarctic bivalve Laternula elliptica from King George Island, Antarctica." Marine Ecology Progress Series 257(2003): 99–110.
- Ahn, In-Young, et al. "Baseline heavy metal concentrations in the Antarctic clam, Laternula elliptica in Maxwell Bay, King George Island, Antarctica." Marine Pollution Bulletin 32.8 (1996): 592–598.
- Ahn, In-Young. "Enhanced particle flux through the biodeposition by the Antarctic suspension-feeding bivalve Laternula elliptica in Marian Cove, King George Island." Journal of Experimental Marine Biology and Ecology 171.1 (1993): 75–90.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Stories of sexual harassment against women in Antarctica highlight issue in science industry".
- ↑ 2.0 2.1 "Newsletter Issue II" Archived 2018-03-31 at the Wayback Machine. (PDF). womeninpolarscience.org.
- ↑ "Southern Exposure".
- ↑ "Antarctica – Southern Exposure". abc.net.au.
- ↑ "Annual Report" (PDF). eng.kopri.re.kr.