Jump to content

India Arie

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
India Arie
India Arie ní Singapore Winehouse Festival in 2011
Ọjọ́ìbíIndia Arie Simpson
3 Oṣù Kẹ̀wá 1975 (1975-10-03) (ọmọ ọdún 48)
Denver, Colorado, U.S.
Orúkọ mírànIndia.Arie
Iléẹ̀kọ́ gígaSavannah College of Art and Design
Iṣẹ́
  • Singer
  • songwriter
Ìgbà iṣẹ́1999–present
Parent(s)
Websitesoulbird.com
Musical career
Irú orin
Labels
Associated acts

India Arie Simpson (ọjọ́ìbí October 3, 1975), tó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bíi India Arie (tàbí india.arie), akọrin àti akọọ̀rọ̀-orin ará Amẹ́ríka.[1] Gbogbo àwọn àwo-orin Arie ti tà iye tó ju mílíọ́mù 3.3 lọ ní Amẹ́ríkà àti mílíọ́mù 10 káàkiri àgbáyé. Ó ti gba She has won four Ẹ̀bùn Grammy mẹ́rin nínú ìpèníyàn 23, èyí tí Àwo-orin R&B Tọ́dárajùlọ wà nínú wọn.[2]

  1. "On A Spiritual And Emotional Journey – India.Arie And Her Music". EF News International. Archived from the original on 2011-11-08. Retrieved 2011-10-28.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Grammy Winner India Arie is coming to Nigeria in June". Bellanaija.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 17 May 2016. Retrieved 2018-12-02.