Ini-Abasi Umotong
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Ini-Abasi Anefiok Umotong | ||
Ọjọ́ ìbí | 15 Oṣù Kàrún 1994 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Calabar, Nigeria | ||
Ìga | 1.74 m | ||
Playing position | Forward | ||
Club information | |||
Current club | Lewes F.C. Women | ||
Number | 15 | ||
Youth career | |||
Birmingham City W.F.C. | |||
2011–2012 | Aston Villa L.F.C. | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2014–2016 | Portsmouth F.C. Ladies | 45 | (54) |
2016–2017 | Oxford United Ladies F.C. | 26 | (17) |
2017–2020 | Brighton & Hove Albion W.F.C. | 46 | (11) |
2020 | Växjö DFF | 15 | (2) |
2021- | Lewes F.C. Women | 17 | (7) |
National team‡ | |||
2015– | Nigeria women's national football team | 7 | (1) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 31 July 2020 (UTC). † Appearances (Goals). |
Ini-Abasi Umotong jẹ́ agbábọ́ọ̀lù lóbìnrin ti órilẹ èdè Nàìjíríà tí a bíní 15,óṣu karùn ní ọdún 1994. Agbábọ́ọ̀lú àlà f'ẹsẹ gbá náà ṣeré fún Club lewes àti team àpapọ Nàìjíríà[1][2].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ini-Abasi kópa nínú Cup finals àwọn obìnrin àgbáyé àti eré ìdíje olympic 2016[3].
- Arábìnrin Ini- Abasi náà gbà goal àkọkọ rẹ̀ fún super falcons nínú eré ìdíje nations tó wáyé ní orílé èdè china[4].
Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://fbref.com/en/players/73699805/Iniabasi-Umotong
- ↑ https://ng.soccerway.com/players/iniabasi-anefiok-umotong/406149/
- ↑ https://www.goal.com/en-ng/news/4093/nigerian-football/2015/05/05/11445802/oparanozie-umotong-arrive-for-rio-2016-olympic-qualifier
- ↑ https://www.goal.com/en-ng/news/4093/nigerian-football/2015/03/16/9856282/nigeria-can-win-womens-world-cup-says-iniabasi-umotong