International and Ibero-American Foundation for Administration and Public Policies

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
International and Ibero-American Foundation for Administration and Public Policies
Fundación Internacional y para Iberoamérica de Administración y Políticas Públicas
Founded1998
HeadquartersMadrid, Spain
Area servedWorldwide
IndustryPublic organization
Owner(s)Government of Spain
Websitefiiapp.org

Àjọ International and Ibero-American Foundation for Administration and Public Policies (FIIAPP) ni ò jẹ́ àjọ gbogbo gbo tí wọ́n dá sílẹ̀ ni abe Spanish State and a member institution of Cooperación Española, lati ọwọ́ orílẹ̀-èdè Spain .[1] Àjọ yí ni ó ti ṣe ìkúnlápá nípa ṣíṣàgbékalẹ̀ iṣẹ́ àkànṣe oríṣiríṣi jákè-jádò àgbáyé, FIIAPP ni ó ń ṣiṣẹ́ labẹ àṣẹ Spanish foreign policy.


Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ajọ yi ni wọn bẹ̀rẹ̀ wọn dá silẹ̀ ní ọdún 1998 lábẹ́ orúkọ Ibero-American Government and Public Policy Foundation, [Fundación Iberoamericana de Gobierno ́y Políticas Públicas], pẹ̀lú ìrankàn àti ṣíṣẹ pẹ̀lú àwọn àjọ àwùjọ gbogbo. Ní ọdún 2000, wọ́n jàn án pọ̀ mọ́ Ibero-American Institute of Public Administration Foundation [Fundación Instituto Iberoamericano de Administración Pública] (tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 1997), tí ó jé kí ó di International and Ibero-American Foundation for Administration and Public Policies (FIIAPP).

Lóní, FIIAPP ti di ọ̀kan gbòógì nínú àwọn àjọ tí ó ṣe agbátẹrù fún àwọn iṣẹ́ àkànṣe oríṣiríṣi fún àjọ European Union ati Spanish Ministry of Foreign Affairs and Cooperation.


Ẹ tún lè wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

http://www.fiiapp.org/ FIIAPP international cooperation projects- http://www.fiiapp.org/proyectos/

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtàkùn ìjásóde[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Authority control