Ira Aldridge

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ira Aldridge
Portrait of Aldridge by James Northcote, 1826
Ọjọ́ìbí(1807-07-24)Oṣù Keje 24, 1807
New York City, United States
AláìsíAugust 7, 1867(1867-08-07) (ọmọ ọdún 60)
Łódź, Poland
Burial placeOld Łódź Cemetery, Poland
Ọmọ orílẹ̀-èdèUnited States, United Kingdom
Iṣẹ́Actor, playwright
Ìgbà iṣẹ́1820s–1867
Olólùfẹ́Margaret Gill, Amanda von Brandt
Àwọn ọmọIra Daniel, Amanda, Ira Frederick, Luranah, Rachael

Ira Frederick Aldridge (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù keje, ọdún 1807, tí ó sì di olóògbé ní ọjọ́ keje oṣù kejọ, ọdún1867) jẹ́ òṣèrékùnrin àti adarí eré orí-ìtàgé tó wá láti orílẹ̀-èdè American. Ó di ìlú-mọ̀ọ́-ká látàrí fífi ẹ̀dá-ìtàn Shakespeate hàn. James Hewlett àti Aldridge ni a lè pè ní àwọn aláwọ̀-dúdú àkọ́kọ́ tí wọ́n máa ń ṣe eré apanilẹ́kún.

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ira Aldridge as Mungo in The Padlock.
Portrait of Ira Aldridge as Mungo, held at the Northwestern University.

Ìlú New York City ní wọ́n bí Aldridge sí, sínú ìdílé ìránṣẹ́ Ọlọ́run Daniel àti Luranah, ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù keje, ọdún 1807. Àmọ́ àwọn ìwé kan sọ pé wọ́n bi sí Bel Air, Maryland.[1]

Iṣẹ́ Aldridge àkọ́kọ́ wáyé ní ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ọdún 1820 pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ Afirika kan, èyí tí William Henry Brown àti James Hewlett ṣe ìdásílẹ̀ rẹ̀.[2][3]

Ní oṣù karùn-ún, ọdún 1825, nígbà tí ó pé ọmọdún mẹ́tàdínlógún, Aldridge ṣe ìfarahàn àkọ́kọ́ rẹ̀ sí ìlú London lásìkò tí wọ́n fẹ́ ṣe àgbéjáde fíìmùOthello.[4] Ní oṣù kẹwàá ọdún 1825 bákan náà, Aldridge tún ṣiṣẹ́ gọbọi mìíràn ní London Royal Coburg Theatre, ó sì di aláwọ̀-dúdú àkọ́kọ́ tí á ṣe ìdásílẹ̀ ara rẹ̀ ní ilẹ̀ àjèjì. Ó ṣe Oroonoko nínú fíìmù The Revolt of Surinam, or A Slave's Revenge.[3]

Aldridge as King Lear
Portrait in pastel, by Taras Shevchenko, 1858

Ìdílé Aldridge[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Ira Daniel Aldridge, 1847–?. olùkọ́. Ó ṣí lọ sí Australia ní ọdún1867.[5]
  • Irene Luranah Pauline Aldridge, 1860–1932. olórin opera.[4]
  • Ira Frederick Olaff Aldridge, 1862–1886. Olórin àti akọ-orin-kalẹ̀.[6]
  • Amanda Christina Elizabeth Aldridge (Amanda Ira Aldridge), 1866–1956. olórin opera, òǹkọ̀wé àti a-ṣẹ̀dá-orin lábẹ́ Montague Ring.[7]
  • Rachael Margaret Frederika Aldridge, b.1868;[8] ó kú ní ìgbà èwe rẹ̀ ní ọdún 1869.[9]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Simmons, William J., and Henry McNeal Turner. Men of Mark: Eminent, Progressive and Rising. GM Rewell & Company, 1887. p657
  2. Nelson, E.S. (2004). In African American Dramatists: An A-to-Z Guide. Santa Barbara, CA: Greenwood.
  3. 3.0 3.1 Hill, Errol G., and James Vernon Hatch. (2003). A History of African American Theatre. Cambridge University Press.
  4. 4.0 4.1 Ross, Alex (July 29, 2013). ""Othello's Daughter"". The New Yorker. https://www.newyorker.com/magazine/2013/07/29/othellos-daughter. Retrieved 14 January 2019. 
  5. Lindfors, 2012; and 2013.
  6. "Prof. Arthur LaBrew, Musicologist | Ellis Washington Report - Part 3". December 28, 2012. 
  7. The Times(London), 10 March 1956, p.9, 'Miss Amanda Ira Aldridge':"Miss Amanda Ira Aldridge, who was the last remaining pupil of the Swedish nightingale, Jenny Lind, died yesterday afternoon in hospital in Surrey, the day before her ninetieth birthday. She was one of the foundation members of the Royal College of Music and taught singing for 65 years. Her most famous pupils were the contralto Marion Anderson and bass baritone Paul Robeson. Using the pen name of Montagu Ring(sic), she composed several works, her most popular work being three African dances. Her last public appearance was on television on April 16, 1954, in Eric Robinson's "Music for You." She was the daughter of the Negro tragedian Ira Aldridge."
  8. England and Wales Births 1868 (1st quarter): Croydon, Surrey, Vol. 2A, p.201, line no.215.
  9. England and Wales Deaths 1869 (4th quarter): Croydon, Surrey, Vol. 2A,p.126, Line no.123.