Jump to content

Iroro Tanshi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Iroro Tanshi
Ọjọ́ìbíỌdún 1984 tàbí 1985
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Conservationist, ecologist
EmployerUniversity Of Benin
Small Mammal Conservation Organisation
AwardsWhitley Award (2021)
Future for Nature Award (2020)

Iroro Tanshi (tí a bí ní ọdun 1984 tàbí 1985)[1] jẹ́ ọmọ Nàìjíríà tí ó ní òye lọ́pọ̀lopọ̀ nípa àwọn àdán, ó sì ń kó nípa àwọn oríṣiríṣi ẹ̀yà àdán ní Afrika. Ó wà lára àwọn ọ̀lùdásílẹ̀ Small Mammal Conservation Organisation (SMACON).[2]

  1. "Nigerian Biologist wins prestigious international prize for nature conservation - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. 2020-12-02. Archived from the original on 2023-02-10. Retrieved 2023-02-10. 
  2. "Iroro Tanshi". Future For Nature (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-12.