Jump to content

Irvingia

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Taxonomy not available for Irvingia; please create it automated assistant
Irvingia
Ogbono nuts
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ e ]
Type species
Irvingia smithii
Synonyms[4]

Irvingella Tiegh.

rvingia malayana in Buon Ma Thuot, Dak Lak, Vietnam

Irvingia je eya igi ti afrika ati Southeast Asian ni idile Irvingiaceae, a sì lè mọ sí àwọn orúkọ bi mangoro igbẹ, mangoro ti afrika, mangoro igbo, dika, mbukpap uyo or ogbono. Won so eso ti o jọ mangoro ti o dé se je ati wipe won ni ọra ati protein lara ninu nuti won.

Eso yi je drupe to Tobi pẹlu ara fibrous. Subtly aromatic nuts re ni a maan gbe ninu orun for itọju,a dé má ta ni odindi tabi ni powderi. A de lẹ gun won sì bí burẹdi dika tabi chocolati Gabon. Ikan inu mucilagi je ki a le lo fún elo obe bi ògbóno. Eyin re ni atun maan tẹ fún òróró.

Igi yìí lè jẹ igi gedu ti a nlo fún ile. A pe irvinga ni eya kan ni 1860

.[5][3] ItO je ara áfríkà àti Southeast Asia[4] TheEya yi ni a fi se ìyí funnard George Irving, a ti o jeRal Navy surgeon.[6]

List of species:[4]

Image Scientific name Distribution
Irvingia excelsa C Africa
Irvingia gabonensis W + C Africa
Irvingia grandifolia C Africa
Irvingia malayana SE Asia
Irvingia robur W + C Africa
Irvingia smithii W + C Africa
Irvingia tenuinucleata W + C Africa
  1. "Tropicos". www.tropicos.org. 
  2. lectotype designated by Bullock, Kew Bull. 14: 43 (18 May 1960).
  3. 3.0 3.1 "Tropicos". www.tropicos.org. 
  4. 4.0 4.1 4.2 "World Checklist of Selected Plant Families: Royal Botanic Gardens, Kew". wcsp.science.kew.org. Archived from the original on 2022-09-05. Retrieved 2023-12-15. 
  5. Hooker, Joseph Dalton. 1860. Transactions of the Linnean Society of London 23: 167 descriptions in Latin, commentary in English
  6. D. Gledhill. The Names of Plants. Cambridge University Press, 2008.

Àdàkọ:Unimelb