Jump to content

Isaac Promise

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Isaac Promise

Promise in 2012
Personal information
Ọjọ́ ìbí(1987-12-02)2 Oṣù Kejìlá 1987
Ibi ọjọ́ibíZaria, Nigeria
Ọjọ́ aláìsí2 October 2019(2019-10-02) (ọmọ ọdún 31)
Ibi ọjọ́aláìsíAustin, Texas, U.S.
Playing positionStriker
Youth career
2003–2005Grays International
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2005–2008Gençlerbirliği93(29)
2008–2010Trabzonspor26(2)
2009–2010Manisaspor (loan)27(6)
2010–2012Manisaspor69(16)
2012–2014Antalyaspor48(11)
2014–2015Al Ahli4(1)
2014–2015Balıkesirspor13(3)
2015–2017Karabükspor12(0)
2016–2017Giresunspor (loan)18(2)
2018Georgia Revolution13(7)
2019Austin Bold20(3)
Total343(80)
National team
2009Nigeria3(1)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Isaac Promise tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kejì oṣù Kejìlá ọdún 1987 tí ó sìn di olóògbé ni ọjọ́ kejì oṣù kẹwàá ọdún 2019 (2 December 1987 – 2 October 2019) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà , àgbàbọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá. [1] Òun ni adarí ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá ọkùnrin tó ṣojú orílẹ̀ èdè Nàìjíríà nínú ìdíje Olympic ọdún 2008, tí wọ́n sìn gba ipò Kejì pẹ̀lú ife-ẹ̀yẹ Fàdákà wá sílé láti ìlú Beijing. Ó gbá bọ́ọ̀lù jẹun fún odidi ọdún Mẹ́rìnlá, púpọ̀ nínú ọdún tó lò gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù tó peregedé ni ó lò ní orílẹ̀-èdè Turkey. Ó ti gbá iye bọ́ọ̀lù tí ó tó Mẹ́tàdínlọ́gọ́rin (77) wọlé sáwọ̀n nígbà ayé rẹ̀.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "NFF hits back at late Isaac Promise’s family - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. 2020-01-11. Retrieved 2020-01-11. 
  2. Otieno, Nereya (2019-10-03). "Former Super Eagle Isaac Promise Dies". OkayAfrica (in Èdè Ṣulu). Retrieved 2020-01-11.