Jump to content

Ismail Ibn Sharif

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Moulay Ismail Ibn Sharif
مولاي إسماعيل بن الشريف
2nd Ruler Alaouite dynasty

Reign 1672 – 1727
Coronation 14 April 1672[1]
Predecessor Al-Rashid Ibn Sharif
Successor Abu'l Abbas Ahmad Ibn Ismail
Reign 1667 – 1672
Spouse among others:
Lalla Aisha Mubarka
Khnata bent Bakkar
Aouda Doukalia
Nassira el-Salwi bint Mohammed el-Heyba
Halima Al Sufyaniyah
Lalla Umm al-Iz at-Taba
Issue
Moulay Mohammed Zeydan
Moulay Abdalmalik
Moulay Ahmed
Moulay Abdallah


Amongst : 525 sons and 343 daughters

Full name
Moulay Ismail I Ibn Sharif Ibn Ali
Era dates
(17th18th Centuries)
House 'Alawi dynasty
Father Sharif ibn Ali
Born c. 1645
Sijilmassa, Morocco
Died 22 March 1727(1727-03-22) (ọmọ ọdún 81–82)
Meknes, Morocco
Burial March 1727
Mausoleum of Moulay Ismail, Meknes
Religion Sunni Islam

Moulay Ismail Ibn Sharif (Lárúbáwá: مولاي إسماعيل بن الشريف‎), tí a bí ní 1645 ní Sijilmassa tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹta oṣù 1727 ní Meknes, jẹ́ Sultan Morocco láti ọdún 1672 sí 1727, gẹ́gẹ́ bi adarí kejì 'Alawi dynasty.[2] Òun ni ọmọkùnrin keje Moulay Sharif ó sì fi ìgbà kan jẹ́ Gómìnà àgbègbè Fez àti àríwá Morocco láti ọdún 1667 títí di ìgbà ikú arákùnrin rẹ̀, Sultan Moulay Rashid ní ọdún 1672. Wọ́n kéde rẹ̀ gẹ́gẹ́ sultan ní Fez, ṣùgbọ́n òun àti Moulay Ahmed ben Mehrez, ẹni kejì tí ó pe ara rẹ̀ ní Sultan jà fún ọ̀pọ̀ ọdún, Moulay Rashid padà fi ayé sílẹ̀ ní ọdún 1687. Moulay Ismail wà lórí oyè fún ọdún márùnléládọ́ta, èyí sì mú kí ó jẹ́ Sultan tí ó pẹ́ lórí oyè jù ní Morocco. Nígbà ayé rẹ̀, Moulay ní ìyàwó tí ó tó ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹta àti ọmọ tí ó tó ẹgbẹ̀rin.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Morocco (Alaoui Dynasty)". www.usa-morocco.org. Archived from the original on 29 August 2005. Retrieved 10 April 2018.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Abun-Nasr, J.M., A History of the Maghrib in the Islamic Period, page 230. Cambridge University Press, 1987