Jump to content

Itunu Hotonu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Itunu Hotonu (bíi ni ọjọ́ kẹji dínlógún oṣù kìíní ọdún 1959) jẹ́ ọmọ ogun orí omi Nàìjíríà[1][2] àti ayàwòrán fún ikọ́lé.[3][4] Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn obìnrin tí ó má je ọmọ ogun orí omi, ó sì wá láàrin àwọn ayàwòrán àkọ́kọ́ fún ẹgbẹ́ ológun orí omi ni Nàìjíríà.[5] Ní oṣù Kejìlá ọdún 2012, ó di obìnrin àkọ́kọ́ ni Áfríkà tí ó má di alábòójútó egbe ológun orí omi.

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Itunu ni ọjọ́ kẹji dínlógún oṣù kìíní ọdún 1959.[6] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Nigeria níbi tí ó tí gboyè ayàwòrán fún ikọ́lé.[7]

Ìtunu jẹ obìnrin àkọ́kọ́ tí ó má darapọ̀ mọ́ National Defence Academy ni abuja ni odun 1985 òun sì akẹ́kọ̀ọ́ to tayọ julọ láàárín àwọn ẹ lẹgbẹ rẹ.[8] Ìtùnú ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó ó má ṣe olùkọ́ ni Armed Forces Command and Staff College ni Jaji.[9][10][11][12] Ní ọdún 2012, ó ń kọ àwọn obìnrin ológun ni orílẹ̀ èdè Libera. Ní oṣù Kejìlá, wọn fi ṣe alábòójútó egbe orí omi ni Nàìjíríà, èyí ló fi jẹ ki o jẹ obìnrin àkọ́kọ́ ni ilé Áfríkà tí ó má de ipò náà.[13][14]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Ambode's wife, others laud 50 years of women's contributions to Lagos". Daily Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-05-19. Retrieved 2020-05-03. 
  2. Editor, Online. "Lagos @ 50: Making heroine of the girl-child New Telegraph Online New Telegraph". New Telegraph (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-03. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. Published. "NIA advised to train, mentor aspiring female architects". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-03. 
  4. Nkasiobi, Oluikpe. "Female Architects Seek Role In Decision-Making Process, Leadership". Independent News.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "THE ROLE OF WOMEN AND GIRLS IN PEACE INITIATIVES IN NIGERIA" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2018-02-19.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "FIRST WOMEN: First Nigerian Woman To Become A Rear Admiral In the Nigerian Navy". Woman Nigeria. 21 September 2016. Archived from the original on 11 March 2019. https://web.archive.org/web/20190311173849/http://woman.ng/2016/09/first-women-first-nigerian-woman-to-become-a-rear-admiral-in-the-nigerian-navy. Retrieved 30 November 2017. 
  7. "Itunu Hotonu: Africa's First Female Admiral's Journey To The Top". Answers Africa. 21 December 2016. https://answersafrica.com/itunu-hotonu-africas-female-admiral.html. Retrieved 30 November 2017. 
  8. "Women who want to break boundaries must be ethical —Rear Admiral Itunu Hotonu » Features » Tribune Online". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-12-25. Retrieved 2020-05-03. 
  9. editor (2019-09-13). "Aisha Buhari Calls for Eradication of Gender Bias in Military". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-03. 
  10. "'If I die, I DIE!'". The Nation Nigeria. 6 May 2017. http://thenationonlineng.net/if-i-diei-die/. Retrieved 29 November 2017. 
  11. "How to achieve gender balance — Hotonu - P.M. News". www.pmnewsnigeria.com. Retrieved 2020-05-03. 
  12. Published. "Hotonu advises women on leadership". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-03. 
  13. "Most Senior Female Military Officer Speaks On Gender Issues In Military". Channels Television. Retrieved 2020-05-03. 
  14. "Adenike Osofisan Deserves National Honour – UI VC -". The NEWS. 2019-06-10. Retrieved 2020-05-03.